
Ìyá Giọji jẹ́ adarí ilé ìṣòwo aṣọ kan, fún ìdí èyí í, ó máa ń lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ àkókò rẹ̀ lórí ìdúró. Ìmá a ṣe itọju àtẹ́lesẹ̀ dáradára àti ìlera àtẹ́lesẹ̀ jẹ́ ǹkan tó ṣe pàtàkì fún láti ní àǹfààní láti lè ṣe iṣẹ́ rẹ̀. Láìpẹ́ sí àkókò náà ni Giọji ní ìmọ̀ nípa àǹfààní tí ó wà fún títọ́jú àtẹ́lesẹ̀ àti bí àṣẹ ń gé èékánná ẹsẹ̀ dáradára ṣùgbọ́n ìyá rẹ̀ tí gé èékánná rẹ̀ nígèékúgè ṣáájú àkókò náà, eléyìí tí ó wá ń fà àtàǹpàkò riro fún un. Ìrora yìí di oun tí ń lé síi, ó nílò láti lọ wá ọ̀nà àbáyọ sí ìṣòro yìí.
Details
- Publication Date
- Apr 23, 2022
- Language
- Yoruba
- ISBN
- 9781435782723
- Category
- Children's
- Copyright
- All Rights Reserved - Standard Copyright License
- Contributors
- By (author): Trey Li
Specifications
- Pages
- 39
- Binding Type
- Paperback Perfect Bound
- Interior Color
- Color
- Dimensions
- US Trade (6 x 9 in / 152 x 229 mm)