
Arábìnrin Kupa jẹ́ ẹni tí ọwọ́ rẹ̀ máa ń dí ṣùgbọ́n a máa wá àyè láti lọ bá ọmọọmọ rẹ̀ Giọji ṣeré. Wọ́n ń padà lọ sí ibùdókọ̀ láti lọ ṣeré àmọ́ àtàǹpàkò ẹsẹ̀ rẹ̀ tí ó ti ń dún fún ọjọ́ pípẹ́ bọ̀ tí bẹ̀rẹ̀ sí í dùn ún gan. Ìrìn àjò rẹ̀ lọ sí ọ̀dọ dókítà lórí rẹ̀ láti ẹ̀yìn wá, pàbó ló já sí ṣùgbọ́n ó sì ní ànfàní mìíràn, kí nin kí ó ṣe?
Details
- Publication Date
- Apr 3, 2022
- Language
- Yoruba
- ISBN
- 9781458312686
- Category
- Children's
- Copyright
- All Rights Reserved - Standard Copyright License
- Contributors
- By (author): Trey Li
Specifications
- Pages
- 39
- Binding Type
- Paperback Perfect Bound
- Interior Color
- Color
- Dimensions
- US Trade (6 x 9 in / 152 x 229 mm)