O ti ń sún mọ́ àsìkò òpin ọdún tí Giọji sì ń fojú sún ìsinmi òpin ọdún, ṣùgbọ́n ṣé àlejò ọ̀ràn kékeré tí ó yọjú sí Giọji yí kò ní ba èròńgbà rẹ̀ lati lo ìsinmi tí ó kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbádùn jẹ́? Ó ṣe àkíyèsí àmì rógódó kékeré tí ó lé ní abẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀ eléyì tí ó ń jẹ́ kí ó nira fún un láti rìn. Giọji ní kòkòrò vẹruka tí ó sì ń bà á lẹ́rù wípé á fa ìdíwọ́ fún òhun lásìkò ìsinmi. Giọji pàdánù ìsinmi rẹ̀ ní ọdún tí ó kọjá látara àìsàn, ǹjẹ́ ó tún máa pàdánù rẹ̀ ni ọdún yìí?
Details
- Publication Date
- Mar 22, 2022
- Language
- Yoruba
- ISBN
- 9781471748264
- Category
- Children's
- Copyright
- All Rights Reserved - Standard Copyright License
- Contributors
- By (author): Trey Li
Specifications
- Pages
- 39
- Binding Type
- Paperback Perfect Bound
- Interior Color
- Color
- Dimensions
- US Trade (6 x 9 in / 152 x 229 mm)